Rom 4:10 YCE

10 Bawo li a ha kà a si i? nigbati o wà ni ikọla tabi li aikọla? Kì iṣe ni ikọla, ṣugbọn li aikọla ni.

Ka pipe ipin Rom 4

Wo Rom 4:10 ni o tọ