9 Ibukún yi ha jẹ ti awọn akọla nikan ni, tabi ti awọn alaikọla pẹlu? nitoriti a wipe, a kà igbagbọ́ fun Abrahamu si ododo.
Ka pipe ipin Rom 4
Wo Rom 4:9 ni o tọ