Rom 7:5 YCE

5 Nitori igbati awa wà nipa ti ara, ifẹkufẹ ẹ̀ṣẹ, ti o wà nipa ofin, o nṣiṣẹ ninu awọn ẹ̀ya ara wa lati so eso si ikú.

Ka pipe ipin Rom 7

Wo Rom 7:5 ni o tọ