Rom 7:6 YCE

6 Ṣugbọn nisisiyi a fi wa silẹ kuro ninu ofin, nitori a ti kú si eyiti a ti dè wa sinu rẹ̀: ki awa ki o le mã sìn li ọtun Ẹmí, ki o má ṣe ni ode ara ti atijọ.

Ka pipe ipin Rom 7

Wo Rom 7:6 ni o tọ