Rom 9:32 YCE

32 Nitori kini? nitori nwọn ko wá a nipa igbagbọ́, ṣugbọn bi ẹnipe nipa iṣẹ ofin. Nitori nwọn kọsẹ lara okuta ikọsẹ ni;

Ka pipe ipin Rom 9

Wo Rom 9:32 ni o tọ