Rom 9:33 YCE

33 Gẹgẹ bi a ti kọ ọ pe, Kiyesi i, mo gbé okuta ikọsẹ ati àpata idugbolu kalẹ ni Sioni: ẹnikẹni ti o ba si gbà a gbọ, oju kì yio ti i.

Ka pipe ipin Rom 9

Wo Rom 9:33 ni o tọ