Dáníẹ́lì 10:7 BMY

7 Èmi Dáníẹ́lì, ni ẹnìkan tí ó rí ìran náà, àwọn ọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú u mi, wọn kò rí i, ṣùgbọ́n ìpayà ńlá dà bò wọ́n, wọ́n sálọ wọ́n sì fi ara pamọ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:7 ni o tọ