Dáníẹ́lì 10:8 BMY

8 Ó sì ku èmi nìkan, tí mo rí ìran ńlá yìí, kò sì ku ohun kankan fún mi, ojú u mi sì rẹ̀wẹ̀sì gidigidi, n kò sì ní agbára mọ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:8 ni o tọ