Dáníẹ́lì 10:9 BMY

9 Nígbà náà, ni mo gbọ́ tí ó ń sọ̀rọ̀, bí mo ṣe tẹ́tí sílẹ̀ síi, mo ṣùn lọ fọnfọn, ní ìdojúbolẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:9 ni o tọ