Dáníẹ́lì 11:20 BMY

20 “Arọ́pò rẹ̀ yóò rán agbowó orí kan jáde láti fi ìdí ipò ọlá ọba múlẹ̀ ṣùgbọ́n ní ìwọ̀n ọdún díẹ̀, a ó pa á run, kì yóò jẹ́ nípa ìbínú tàbí nínú ogun.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:20 ni o tọ