Dáníẹ́lì 11:21 BMY

21 “Ẹni tí kò níláárí kan yóò rọ́pò rẹ̀, ẹni tí a kò tí ì fi ọlá ọba fún rí. Yóò sì gbógun sí ìjọba nígbà tí ọkàn àwọn ènìyàn balẹ̀ láìbẹ̀rù, yóò sì gbà á pẹ̀lú àrékérekè.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:21 ni o tọ