Dáníẹ́lì 12:8 BMY

8 Èmi gbọ́, ṣùgbọ́n kò yé mi. Nígbà náà ni mo bèèrè pé, “Olúwa mi, kí ni yóò jẹ́ àbábọ̀ àwọn nǹkan wọ̀nyí?”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 12

Wo Dáníẹ́lì 12:8 ni o tọ