Dáníẹ́lì 12:9 BMY

9 Ó sì dáhùn pé, “Má a lọ ní ọ̀nà rẹ, Dáníẹ́lì nítorí tí a ti pa ọ̀rọ̀ náà dé, a sì ti fi èdìdì dìí di ìgbà ìkẹyìn.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 12

Wo Dáníẹ́lì 12:9 ni o tọ