Dáníẹ́lì 2:16 BMY

16 Nígbà náà ni Dáníẹ́lì wọlé tọ ọba lọ, ó sì tọrọ kí ọba fún òun ní ààyè, òun yóò fi ìtumọ̀ àlá náà hàn fún ọba.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:16 ni o tọ