Dáníẹ́lì 2:17 BMY

17 Nígbà náà ni Dáníẹ́lì padà lọ sí ilé e rẹ̀, ó sì sọ fún àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀ Hananíáyà, Míṣáẹ́lì àti Ásáríyà.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:17 ni o tọ