Dáníẹ́lì 2:18 BMY

18 Ó sọ fún wọn pé kí wọn bèèrè fún àánú Ọlọ́run ọ̀run nípa àsírí náà, kí ọba má ba à pa àwọn run pẹ̀lú àwọn amòye Bábílónì.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:18 ni o tọ