Dáníẹ́lì 2:4 BMY

4 Nígbà náà ni àwọn awòràwọ̀ dá ọba lóhùn ní èdè Árámáíkì pé, “Kí ọba kí ó pẹ́! Sọ àlá yìí fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ àwa yóò sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún ọ.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:4 ni o tọ