Dáníẹ́lì 2:5 BMY

5 Ọba dá àwọn awòràwọ̀ lóhùn pé, “Ohun náà ti kúrò lórí mi: tí ẹ̀yin kò bá sọ àlá náà àti ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi, èmi yóò gé e yín sí wẹ́wẹ́, ilé e yín yóò sì di ààtàn.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:5 ni o tọ