Dáníẹ́lì 2:6 BMY

6 Ṣùgbọ́n tí ẹ̀yin bá sọ àlá náà àti ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi, èmi yóò fún un yín ní ẹ̀bùn, ọrẹ àti ọláńlá tí ó pọ̀. Nítorí náà, ẹ sọ àlá náà àti ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:6 ni o tọ