Dáníẹ́lì 2:47 BMY

47 Ọba wí fún Dáníẹ́lì pé, “Dájúdájú Ọlọ́run rẹ ni Ọlọ́run àwọn ọlọ́run àti Olúwa àwọn ọba gbogbo àti olùfihàn àwọn àsírí, nítorí tí ìwọ lè fi àsírí yìí hàn.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:47 ni o tọ