Dáníẹ́lì 2:48 BMY

48 Nígbà náà ni ọba gbé Dáníẹ́lì ga, ó sì fún un ní ẹ̀bùn ńlá tí ó pọ̀. Ó sì fi ṣe olórí i gbogbo agbègbè ìjọba Bábílónì àti olórí gbogbo àwọn amòye Bábílónì.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:48 ni o tọ