Dáníẹ́lì 3:1 BMY

1 Nebukadinéṣárì ọba gbẹ́ ère wúrà kan, èyí tí gíga rẹ̀ tó àádọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́, tí fífẹ̀ rẹ̀ tó ẹsẹ̀ mẹ́fà, ó sì gbé e kalẹ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Dúrà ní agbègbè ìjọba Bábílónì.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:1 ni o tọ