Dáníẹ́lì 3:2 BMY

2 Nígbà náà ni ọba ránṣẹ́ pe àwọn ọmọ aládé, àwọn olóyè, àwọn ìgbìmọ̀, àwọn baálẹ̀, àwọn balógun, àwọn onídàájọ́, àwọn olùtọ́jú ìṣúra àti gbogbo àwọn olórí agbègbè ìjọba láti wá sí ibi ìyàsímímọ́ ère tí ọba Nebukadinésárì gbé kalẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:2 ni o tọ