Dáníẹ́lì 3:3 BMY

3 Nígbà náà ni àwọn ọmọ aládé, àwọn olóyè, àwọn onímọ̀ràn, àwọn olùtọ́jú ìṣúra, àwọn onídàájọ́ àti gbogbo àwọn olórí agbègbè ìjọba, wọn péjọ láti ya ère tí Nebukadinésárì ọba gbé kalẹ̀ sí mímọ́, gbogbo wọn sì dúró síwájú u rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:3 ni o tọ