Dáníẹ́lì 3:4 BMY

4 Nígbà náà ni a kéde kígbe sókè wí pé, “Ohun tí a paláṣẹ fún un yín láti ṣe nìyìí, gbogbo ènìyàn, orílẹ̀ èdè àti èdè gbogbo:

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:4 ni o tọ