Dáníẹ́lì 3:5 BMY

5 Bí ẹ̀yin bá ti gbọ́ ohùn ìwo, fèrè, dùùrù, ohun èlò, kí ẹ wólẹ̀ fún ère wúrà tí ọba Nebukadinésárì gbé kalẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:5 ni o tọ