Dáníẹ́lì 3:21 BMY

21 Nígbà náà ni a dè wọ́n pẹ̀lú àwọ̀tẹ́lẹ̀ wọn, ṣòkòtò, ìbòrí àti àwọn aṣọ mìíràn, a sì jù wọ́n sínú iná ìléru.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:21 ni o tọ