Dáníẹ́lì 3:22 BMY

22 Nítorí bí àsẹ ọba ṣe le tó, tí iná ìléru náà sì gbóná, ọwọ́ iná pa àwọn ọmọ ogun tí wọ́n mú Sádírákì, Mésákì àti Àbẹ́dinígò lọ.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:22 ni o tọ