Dáníẹ́lì 3:23 BMY

23 Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta náà Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò ṣubú lulẹ̀ sínú iná ìléru náà pẹ̀lú bí a ṣe dè wọ́n.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:23 ni o tọ