Dáníẹ́lì 3:24 BMY

24 Nígbà náà ni ó ya Nebukadinéṣárì ọba lẹ́nu, ó sì yára dìde dúró, ó bèèrè lọ́wọ́ àwọn ìgbìmọ̀ rẹ̀ pé, “Ṣe bí àwọn mẹ́ta ni a gbé jù sínú iná?”Wọ́n wí pé, “Òtítọ́ ni ọba.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:24 ni o tọ