Dáníẹ́lì 3:25 BMY

25 Ó sì wí pé, “Wò ó! Mo rí àwọn mẹ́rin tí a kò dè tí wọ́n ń rìn ká nínú iná, ẹnì kẹrin dàbí ọmọ Ọlọ́run.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:25 ni o tọ