Dáníẹ́lì 5:10 BMY

10 Nígbà tí ayaba gbọ́ ohùn ọba àti àwọn ọlọ́lá rẹ̀, ó wá ilé àsè wá. Ó wí pé, “Kí ọba kí ó pẹ́! Má ṣe jẹ́ kí inú un rẹ bàjẹ́, má sì ṣe jẹ́ kí ojú u rẹ fàro.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:10 ni o tọ