Dáníẹ́lì 5:5 BMY

5 Lójijì, ìka ọwọ́ ènìyàn jáde wá, ó sì ń kọ̀wé sára ẹfun ògiri ní ẹ̀gbẹ́ ibi tí àtùpà ń dúró ní ààfin ọba. Ọba ń wo ọwọ́ náà bí ó ṣe ń kọ ọ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:5 ni o tọ