Dáníẹ́lì 6:13 BMY

13 Nígbà náà, ni wọ́n sọ fún ọba pé, “Dáníẹ́lì, ọ̀kan lára ìgbékùn Júdà, kò ka ìwọ ọba sí, tàbí àṣẹ ẹ̀ rẹ tí o fi ọwọ́ sí. Òun sì tún ń gba àdúrà ní ẹ̀mẹ́ta lójúmọ́.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 6

Wo Dáníẹ́lì 6:13 ni o tọ