Dáníẹ́lì 6:14 BMY

14 Nígbà tí ọba gbọ́ èyí, inú un rẹ̀ bàjẹ́ gidigidi; ó pinnu láti kó Dáníẹ́lì yọ, títí òòrùn fi rọ̀, ó sa gbogbo ipá a rẹ̀ láti gba Dáníẹ́lì sílẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 6

Wo Dáníẹ́lì 6:14 ni o tọ