Dáníẹ́lì 6:16 BMY

16 Nígbà náà, ni ọba pàṣẹ, wọ́n sì mú Dáníẹ́lì, wọ́n sì sọ ọ́ sínú ihò kìnnìún. Ọba sì sọ fún Dáníẹ́lì pé, “Kí Ọlọ́run rẹ tí ìwọ ń sìn nígbà gbogbo kí ó gbà ọ́!”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 6

Wo Dáníẹ́lì 6:16 ni o tọ