Dáníẹ́lì 6:17 BMY

17 A sì gbé òkúta kan wá, wọ́n sì fi dí ẹnu ihò náà, ọba sì dí i pa pẹ̀lú òrùka èdìdì rẹ̀ àti pẹ̀lú òrùka àwọn ọlọ́lá rẹ̀, nítorí kí a má ṣe yí ohunkóhun padà nítorí i Dáníẹ́lì.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 6

Wo Dáníẹ́lì 6:17 ni o tọ