Dáníẹ́lì 9:3 BMY

3 Nígbà náà, ni mo yípadà sí Olúwa Ọlọ́run, mo bẹ̀ẹ́ pẹ̀lú àdúrà àti ẹ̀bẹ̀, pẹ̀lú ààwẹ̀, aṣọ ọ̀fọ̀ àti eérú.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:3 ni o tọ