Ékísódù 18:10 BMY

10 Jẹ́tírò sì wí pé, “Ìyìn ni fún Olúwa, ẹni tí ó gba yín là kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Éjíbítì àti lọ́wọ́ Fáráò, ẹni tí ó sì gbà àwọn ènìyàn là kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Éjíbítì.

Ka pipe ipin Ékísódù 18

Wo Ékísódù 18:10 ni o tọ