Ékísódù 18:11 BMY

11 Mo mọ nísinsìnyìí pé Olúwa tóbi ju gbogbo àwọn òrìṣà lọ; nítorí ti ó gba àwọn ènìyàn rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìgbéraga àti ìkà àwọn ará Éjíbítì.”

Ka pipe ipin Ékísódù 18

Wo Ékísódù 18:11 ni o tọ