Ékísódù 18:7 BMY

7 Mósè sì jáde lọ pàdé rẹ̀, ó tẹríba fún un, ó sì fi ẹnu kò ó ni ẹnu. Wọ́n kí ara wọn, wọ́n yọ̀ mọ́ ara wọn, wọ́n sì wọ inú àgọ́ lọ.

Ka pipe ipin Ékísódù 18

Wo Ékísódù 18:7 ni o tọ