Ékísódù 18:8 BMY

8 Mósè sọ fún àna rẹ̀ nípa ohun gbogbo ti Olúwa tí se sí Fáráò àti àwọn ará Éjíbítì nítorí Ísírẹ́lì. Ó sọ nípa gbogbo ìṣòro tí wọn bá pàdé ní ọ̀nà wọn àti bí Olúwa ti gbà wọ́n là.

Ka pipe ipin Ékísódù 18

Wo Ékísódù 18:8 ni o tọ