Ékísódù 2:19 BMY

19 Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ará Éjíbítì kan ni ó gbà wá sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn darandaran, ó tilẹ̀ ràn wá lọ́wọ́ láti fa omi àti láti fún agbo ẹran ní omi.”

Ka pipe ipin Ékísódù 2

Wo Ékísódù 2:19 ni o tọ