Ékísódù 24:18 BMY

18 Nígbà náà ni Mósè wọ inú ìkùùkuu náà bí ó ti ń lọ ní orí òkè. Ó sì wà ni orí òkè náà ni ogójì ọ̀sán àti ogójì òru.

Ka pipe ipin Ékísódù 24

Wo Ékísódù 24:18 ni o tọ