Ékísódù 28:28 BMY

28 Wọn yóò sì so òrùka ìgbàyà mọ́ òrùka ẹ̀wù èfòdì pẹ̀lú ọ̀já aláró, pa á pọ̀ mọ́ ìgbànú, kí a má ba à tú ìgbàyà náà kúrò lára ẹ̀wù èfòdì náà.

Ka pipe ipin Ékísódù 28

Wo Ékísódù 28:28 ni o tọ