Ékísódù 28:29 BMY

29 “Nígbà kúgbà tí Árónì bá wọ ibi mímọ́, òun yóò ru orúkọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (Ẹ̀yà méjìlá) ní gbogbo ọ̀kan rẹ̀ ni ìgbàyà ìpinu bí ìrántí nígbà gbogbo níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin Ékísódù 28

Wo Ékísódù 28:29 ni o tọ