Ékísódù 28:33 BMY

33 Ṣe pómégánátè ti aṣọ aláró, ti elésèé àlùkò àti ti òdòdó yí ìsẹ́ti ọ̀já àmùrè náà ká, pẹ̀lú aago wúrà láàrin wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 28

Wo Ékísódù 28:33 ni o tọ