Ékísódù 36:38 BMY

38 wọ́n sì ṣe òpó márùn-ún pẹ̀lú ìkọ́ wọn. Wọ́n bo orí àwọn òpó náà àti ìgbànú wọn pẹ̀lú wúrà, wọn sì ṣe ihò ìtẹ̀bọ̀ márùn-ún wọn ní idẹ.

Ka pipe ipin Ékísódù 36

Wo Ékísódù 36:38 ni o tọ