Ékísódù 40:37 BMY

37 ṣùgbọ́n tí àwọ̀ọsánmọ̀ kò bá gòkè wọn kò ní jáde títí di ọjọ́ tí ó bá gòkè.

Ka pipe ipin Ékísódù 40

Wo Ékísódù 40:37 ni o tọ