Ékísódù 40:38 BMY

38 Nítorí náà àwọ̀ọsánmọ̀ Olúwa wà lórí Àgọ́ ní ọ̀sán, iná sì wà nínú àwọ̀ọsánmọ̀ ní òru, ní ojú gbogbo ilé Ísírẹ́lì ní gbogbo ìrìnàjò wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 40

Wo Ékísódù 40:38 ni o tọ